Bibeli Mimo - TWOGBS Bibeli Mimo - TWOGBS

Bibeli Mimo - TWOGBS

Onítumò

    • $1.99
    • $1.99

Publisher Description

BÍBÉLÌ MÍMÓ̩

ONÍTUMÒ̩


MÁJÈ̩MÚ LÁÉLÁÉ ÀTI TITUN


©2009

© Revised 2010

© TWoGBs 2009-2010


No part of this Bible may be reproduced by photocopying 

or by mechanical or by electronics means or in any other form 

without prior written permision from the Publisher


iBooks Author Version


ISBN 978-1-908470-05-8

 

BÍBÉLÌ MÍMÓ̩ ONÍTUMÒ̩

Typeset and Printed by The Word & The Word of God Bible Society 


The Word of God Bible Society 

Charity Registered No. 1133009 Company No. 6824905

wogbs@live.co.uk

===

Isé̩ yìí jé̩ ogún The Word of God Bible Society, a KÒ sì gbo̩dò̩ dà á ko̩ fún eniké̩ni tàbí fún ò̩ré̩.


Lò ó bí i ìwé tí ó jé̩ wí pé e̩nìkan-soso ni ó lè lò ó lé̩è̩kan. Má s̩e lò ó ju nínú kò̩mpútà kan-soso lo̩ lé̩è̩kan.


A kò fi às̩e̩ fún e̩niké̩ni láti s̩e àtúntè̩, tabí láti s̩e àdàko̩, tàbí láti tún Bíbélì Mímo̩ Onítumò̩ tí a kà yìí kà sí inú kò̩pútà, tàbí kí á ká a sí inú káséè̩tì (cassette), è̩ro-ìbánisò̩rò̩-alágbéká, ero̩-orin-alágbéká, tàbí CD/DVD, tàbí irúfé̩ ero̩ tí a lè fi nkan tàbí ò̩rò̩ pamó̩ sí; tàbí fún gbígbó̩ lòdì sí èròǹgbà ti irúfé̩ mìíran tí a so̩, tàbí tí a kò so̩ nígbà pínpín ò̩rò̩ Bíbelì yìí nigbà tí a tà á. E̩ni tí ó bá s̩e lòdì sí èyí fi hàn gban̄gba wí pé kò fé̩ ìtànká ìhìn-rere. 


Owó tí a bá rí nínú títa Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ yìí ni a yóó lò fún títè̩síwájú ìpín-fún-ni Ò̩rò̩ Olórun. Fi e̩nu kò pèlú ìlérí fún Jésù Krístì Olúwa wí pé o ra ètò Bíbélì yìí àti kíkà rè̩ ló̩nà è̩tó̩, àti wí pé o kò ní fi fún e̩niké̩ni ló̩nà àìtó̩.


A ń retí bí O̩ló̩run bá ti fi sí yín ní o̩kàn: ò̩rò̩ ìgba-ni-ní-yànjú, ìrànló̩wó̩, è̩bùn, owó, ètò è̩ro kò̩mpútà fún Bíbélì yìí, tàbí ohun èlò fún às̩eyo̩rí àti ìtè̩síwájú is̩é̩ Bíbélì Onítumò̩ yìí láti ò̩dò̩ yín. Gbogbo onírúurú tàbí irúfé̩ àdàko̩ ni òfin yìí lòdì sí.


'Sí òfin àti sí è̩rí, bí wo̩n kò bá so̩ gé̩gé̩ bíi ò̩rò̩ yìí; nítorí tí kò sí ìmó̩lè̩ nínú wo̩n ni' (Ìsáíàh 8:20).

===

These files are the property of The Word of God Bible Society and may NOT be copied or shared with anyone or your friends.


Treat this file like a book, only one user at a time. Do NOT install on more than one computer at a time.


This Bibeli Onitumo text and recordings for computers and Mp3 players should not be copied or stored in any format for any system known or unknown for storage or play-back; the instruction with the distribution medium should be strictly adhered to. The purchased copy can however be used in churches during services or for evangelism; for the blind, and / or those that cannot read. Anyone who violates these conditions shows that he does not want the propagation of the gospel.


The money raised on this Bible project is used for further distribution of the Word of God. Please affirm to the Lord Jesus Christ that you have legally purchased this Bible module and its Audio files and will not distribute it illegally to any un-authorised people.


Advice, help, donations, payment for these modules, and suggestions are welcome on any aspect of this project as God lays it on your heart.


'To the law and to the testimony: if they speak not according to this word, it is because there is no light in them' . (Isaiah 8:20).

====

GENRE
Religion & Spirituality
RELEASED
2009
May 31
LANGUAGE
AF
Afrikaans
LENGTH
1,709
Pages
PUBLISHER
The Word and The Word of God Bible Society
SELLER
The Word of God Bible Society
SIZE
115.6
MB